ASIRI NLA TOWA LARI AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON
ASIRI NLA TOWA LARIN AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON 1. OMI ATI OMI Ibeere kan timo ma nbi awon onirawo kan na toba fe ferawon nipe, Shey won setan lati se suuru fun arawon.... Tori ija amawaye larin won, kosi biwon sefese ti won ba nja ni gbogbo igba..... Nkan lema lo dede fun... Sugbon tiwon bagbo arawon y,tiwon sin ran arawon lowo Lori biwon ose mani ilosiwaju..... Ibagbe won ma roru.. Osima mu ire topo wani idile won. 2 OMI ATI ERUPE Won le fe arawon,won sile Jo da ise po, tiwon kobati je ewo tabi ki enikan mase sina.sugbon iyepe ni ibase yi ma rorun fun julo. 3 OMI ATI INA omi ni pa oro Ina..... Gbogbo wa lama pe irawo omi ati Ina kobarawon mun, beni kosi irawo ina ati omi kobarawon mun sugbon irawo ina kan wa to anfani lati fe irawo omi but oni side effects re o. iseda ina kan wa tojewipe ibasepo todan moran wa laarin oun ati omi koda won le da ise po beni won le fe arawon , sugbon tiwon je ewo ati wonko tele ofin ati ilana irawo...