ASIRI IRAWO AFEFE
ASIRI IRAWO AFEFE LAPAPO(GENERAL SECRETS BEHIND AIR SIGNS)
Arin irin ajo aiye, oni mimo aiye, ojogbon eniyan, cel celebrities
ebrities ma npo ninu won, irawo lile ni irawo yi.. Ori won sima nle, lafi ni kiwon ma bo ori won dada.... Ogun okin sise lara apakan ninu irawo yi.... Awon agbalagba omo na po ninu irawo yi
Opolopo won ama ni idojuko ati isoro topo gan Debi ipe aiye afe suwon... Sugbon tiwon base gun pere... Aiye afi olawon toro ni... Bi ola ati okiki won ase to.. Sugbon opolopo won koma oju ona.
Oba ni irawo yi je lawujo irawo toku, alagbara tio mawa nipo nla nla niwon, won osimari ero ngbawon lopin igbati wonkobati je ewo(forbidden) tabi lonkan ewo tabi se nkan ewo. Ogun okin sise lara opolopo won tori iseda won lagbara gan ori won sile... Tori re lofise pataki kiwon ma bo ori won...
Saara sise se dandan funwon tori ki ona maba madimawon.. Kiwon ma se saara dada leyi toba iseda irawo won mun tori kiwon maba mari ifaseyin ninu irin ajo aiye won..
Wo kogbodo masa fun aso funfun (white) ni wiwo tori ki eto oro aiye won maba dojuru,
Irawo yi kogbodo je eniyan tioma joko si ojukan tori kadara irawo re kofara ma... Afefe ma nrin kakiri ni.. Ori irin ajo ni opolopo won tima nri oore aiye won..
Onirawo yi kogbodo mawo aso totako irawo won tori alakala, ikorira, ìbínú ati ija, ifaseyin.
Gbogbo awon nkan wonyi ni yio masele si onirawo yi toba nwo aso tikoba kadara irawo re mun.
Biwon se je alawada awon eniyan ni awon eniyan tun ma nse ilara ebun tiafunwon, awon eyan amafe se ika funwon lopolopo igba..
ELEGBE INU IRAWO AFEFE
Idaji omo tiabi ninu irawo yi ni won ni egbe.. Awon omo elegbe inu irawo yi amani isoro ibujoko, okunrin won ama ko obinrin kiri (adultery)
AWON EGBE TIO MA NSABA WA NINU IRAWO YI NI
-emere ofurufu
-iranse aje
Igi aje (wealth)
Omi anu etc...
Irawo yi nise pelu omi pupo tori afefe ati omi joma nwa ni, tori afefe wa ninu omi.... Nje iwo ma Asiri towa larin irawo omi ati afefe?... sugbon kise oro eni...
AJE ARA IRAWO AFEFE
Aje ara irawo afefe wani owo (hand) re...gbogbo igba ti aje yi bati funwon ni apere ati Ikilo ni owo ama hunwon... Gege bi apeere
Oore kan lema bo Lona fun e tabi kio fe gba owo nla kan.. Owo ama hun e lasiko igbayen..
Ti eyan ba se nkan ewo tabi awon kan ti otako irawo re... Owo lema hun e..
ASIRI WO LOWA LARIN IRAWO AFEFE METETA
Irawo afefe onibinu (aquarius)
Planet 🌔 to nje oba irawo yi ni (Uranus)
Irawo yi lama si sango (god of thunder)..
Awon nkan toroma planet irawo yi ni (rebellion for justice, humanitarial ideals, upheaval) lofi jepe gbogbo awon to nlo irawo yi ma n ni lakayi lati da ejo(justice) ati IMO nipa ofin (law), wonma fi lakayi won sise tabi se igbese lati tesi waju... Etc..
Asiri po labe irawo kokan, iwo nikio se iwadi irawo re.. Kio le ma nkan toye kioma se lasiko
IRAWO AFEFE ALAWADA( GEMINI) ♊️
Irawo ibeji (the twins)
Planet 🌔 to nje oba irawo yi ni mercury
Irawo yi lama si irawo aje (wealth) tori dandan ni owo lodowon, won gbodo mari owo Lona irorun, irawo yi je Okan ninu awon irawo ti awon agbalagba ma ndalamu ni won efi tete rojutu oro aiye won....
Kini nkan towa ninu planet 🌔 won?
Irawo yi ni afun ni IMO oro siso (best communicator and information) won ma bi ase ma n fi lakayi gbe oro jade, bi asema nse iwadi nkan topama...
Opolopo won ni imisi olohun lara ( spiritual sign) won ama gba message ninu Okan tabi loju ala (dream)..... Ejeki kindaduro bayen na..
Asiri po labe irawo kokan ti aye kogbami lati maso.... Iwo tiobafe ma nipa irawo re, message mi privately fun iwadi.
IRAWO AFEFE MARIMIFIN (LIBRA)
Irawo osuwon(scale)
Planet 🌔 ton je oba irawo yi ni (Venus)
Irawo yi wa ninu awon irawo to nje oba ife (love), idagbasoke (fertility) ati AYO (joy)... Won tunje oloro (wealth)
Irawo yi je alagbara ati eyan lile, won burugan ni (very wicked people) isedawon le pupo.... Ninu awon irawo ti oribibo se pataki fun ni irawo yi wa...
Melo nimofe so ninu asiri irawo kokan
Yatosi asiri toso gbogbo irawo afefe papo, irawo kokan ni asiri tie tikopapo mo irawo toku.. Iwadi loma so gbogbo Iyen fun e, kosi aye fun emi lati maso tori asiri ni, iwo tio bafe ma asiri irawo re.. Message mi fun iwadi irawo..
KINI AWON ASIRI TOYE KIO MA NIPA IRAWO RE
Iwa ati isesi ti irawo re farama kio ma wu lawujo irawo toku..
Awon ounje kan wa tikoba ilera (health) irawo mi mun... Se iwo mo?...
Sara ati ise igbiyanju toba kadara irawo re mun...
Ise toroma kadara re...
Aso toye kioma wo ati eyi totako kadara irawo re...
Bawo ni wase malo igbese aiye re laisi wahala...
Kinni awon nkan tikoye kioma se tole sokunfa alakala ati ifaseyin..
Iru aje wo lowa ninu irawo re, ibolowa , kini ewo re ati pe bawo ni asema nse itoju re....
Iru iyawo tabi oko toba irawo re mun...
Kini lucky number re ati lucky day re...
Awon ojowo lodara fun e lati mase sara tabi dawo le ise igbiyanju...
ETC...
Gbogbo awon nkan yi loye kio ma gege bi eniyan to nle ojo iwaju rere... Itosona ojo ola ni irawo je.
Gbogbo asiri nipa irawo ile(house) kokan lati gbejade sinu iwe (PDF EBOOK) fun eniyan toba nife si iwe na... Iwe yen wanile fun tita... (Visit our page if you have interest)

Comments
Post a Comment