ÀJÉ (WEALTH)
ÀJÉ (WEALTH)
Aje olokun asoro di ayo, wafi ile mise ibugbe.... Se gbogbo wa nani ama ewo aje? ,shey gbogbo wa lama itoju aje?.
Aje yi je nkan tio ma sise owo wafun eda eniyan, ti ogo eniyan sima tete buyo ise keke re owo nla, koda eniyan lema ni ise gidi kan lowo ti owo asima wole ni onakona, eniyan ti aje ba wa ni arare tikosi je ewo aje tabi awon ti ika eda kofi oju si lara debi tiwon madena lati ri aje re lo, iru eniyan be mama ri owo ni ona tiko ro rara... Iru won ni won ma ntete ni owo lowo... Ni owo toje owo nla.
Eniyan tio ba ri aje lo, koni damu laiye kio to ni owo.
Àjé je nkan pàtàkì tii kii kúrò lára ẹniyan niwọn bá igba tii ẹda bati tètè se iwadi irawo re ati akosejaiye kiole ma nkan toye komase...
nje iwoma pe aje ama kuro lara eyan tiosi fi eniyan sile patapata.
AWON ONA TI AJE (WEALTH) FI MA NKURO LARA ENIYAN
1) ti eyan koba se awari ara re debi tio ma ma awon nkan totako irawo ati kádàrá re, tori gbogbo eda loni awon asiri topamo sinu kakara won ... Osese ki aje fi oni tohun sile patapata
2)awon agbalagba ama se akoba fun irawo elomi, tiwon madena atiri aje ara re lo, iru awon eniyan yi ni ogun idile abi ogun aiye ndamu.
3)ofa aiye wa lara elomiran tikoni je kio ri aje re lo... Gbogbo igbinyanju re koni yo tori ofa aiye towa lara re...
4)elomi tije ewo irawo re, eleyi madena lati ri aje re lo, gbogbo igba toba tin se nkan totako irawo re ni ona atilosi waju lenu ise tabi ninu aje madiku.
5)nje ema pe kise gbogbo omo léle yokuro ninu egbe.... Ojo tiwon tiyo omo mi kuro ninu egbe ni aje tikuro larare tori aje to nlo ninu egbe lowa... Idi niyi ti opolopo awon omo elegbe fi ma n ni aje lara tori egbe loni aje tiwon nlo....
6)ewo aje (wealth)... Aje gan gan fun rara re ni ewo tie.... Sugbon koye opolopo eniyan, gbogbo igba toba tin se nkan ti aje kofi arama ni aje atima fi onitohun sile, aje ni ewo ode ni itoju tie...
7)ninu nkan totun ma nfa ki aje kuro lara eniyan ni (SEX) kise gbogbo eniyan logbodo ma gun orire gege bi omo alaje tioje... Kisise gbogbo eniyan ni olema bani ajosepo.. Aje kofi arama gbogbo awon nkan won yi... Oropo ninu iwe kobo...
Se iwadi irawo re ati akosejaiye kiole tete ri onalo layere
Etc....
DIE NINU ONIRANRAN AJE (WEALTH)
Erisirisi ni awon aje wonyi besi ni ara otooto niwon.
-Omo aje
-aso aje
Opa aje
Igba aje etc..
Ninu awon aje ara omo elegbe ni... Igi aje, iranse aje... Etc..
gbogbo awon aje yi loni ara awon eniyan to ma nwa... Apere ati àkíyèsí loma jeki o ma iru aje towa lara re, iwadi ama so nigbami ati iru egbe ti eniyan bawa..
Sasa ni irawo tikoni aje tie... Ode ni ibi ti oma nwa lara onirawo kokan... sugbon oroyen kise oni....
Pupo ninu awon omo elegbe loni erisirisi awon aje yi lara ode ni biwon tima nlo..
BIOSE NBAMI FOLLOW PAGE YI TIOSIN BAMI SHARE POST YI..... MOGBA LADURA PE... AJE KONI FIESILE LO
Gbiyanju kiose iwadi irawo re ati akosejaiye kiole ma iru aje ati awon kan to roma kádàrá re...
iwe ASIRI IRAWO MI wanile fun tita.... e message mi privately tie ba nifesi
Fun iwadi nipa irawo re ati akosejaiye, spiritual consultation.... Message me privately

Comments
Post a Comment