Posts

Showing posts from July, 2024

ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)

  Kini Anpeni Ori (Head)  Gangan Ori ni oba ara, ori yi ni oje engine to n control ara wa, ori lo npase bi ara sema lo isemi, ti ori bati baje.. Gbogbo eya (part) ara toku na ko wulo ma... Ori je asiwaju tori ohun ni olohun fise olutosona eda nile aiye...ti ori eni bagba abode, isemi eniyan yen mawa ninu wahala ati idamun ni..   Tori re ni agbodo fi mojuto eleda wa tabi iseda wa, tori re ni awon baba wa fi pataki ori..  Awon baba wa amaso pe (ori ni apesin, ori ni gbani, orimi matakomi, orimi magba abode)  Adura ti awon baba wa ma nse Nipa ori kise kekere tori iseda eniyan se pataki ninu aiye..  KINI ANPENI ORI BIBO..  Ori bibo je ona ti awon baba wa ma ngba lati lefi be ori (head)  tabi se etutu ori.. Ni asiko ti nkan bale ma eda, ti atije ati mu ba nira tabi ti orire ba gba abode..  Opolopo eniyan ni ori re le pupo, tosi ye kioma bo orire lorekore tori iseda re le, sugbon opolopo eniyan koma iru iseda ti ohun nlo debi toma mape oye ki ...

IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)

  Nje iwo tie se iwadi kankan kio to ma ni ibalopo (s*x) pelu eni tio ndate lowo... Opolopo yin kan ni ibalopo pelu eniyan toba pade tabi towu e, nje iwo ma iru irawo ti eniyan yen nlo tabi iru eniyan toje kioto ma ni nkan papo pelu re, opolopo ogun aini ilosiwaju to nja elomiran... Kise ogun aiye tabi ogun idile bikise pe afowofa lofi koba arare..  Ibalopo lasan gan ole pa kadara eniyan da si aburu..  Gbogbo irawo loni irawo totako tie sugbon ikan ju ikan lo, gbogbo irawo ni kofara ma sina sise (adultery) sugbon elomiran mu ni igbadun, sina sise kun nkan ti opolopo elomi kofi ni ilosiwaju ninu irin ajo aiye re...  tori kosi bi wase mase sina kiri ti oni ni ibalopo pelu eniyan ti kadara irawo re tako tie.. Odeni ma tori nkan towu e lo nse.  Gbogbo nkan koni ogun sise... Akiesi ati ima nipa arare na se pataki ...  KINI AWON NKAN TI AMA NWO KIATOLE SOPE AWON IRAWO YI BARAWON MU DADA... Awon nkan meta kan wa tia gbodo wo kato sope irin ajo won papo lati fera...