ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)
Kini Anpeni Ori (Head) Gangan Ori ni oba ara, ori yi ni oje engine to n control ara wa, ori lo npase bi ara sema lo isemi, ti ori bati baje.. Gbogbo eya (part) ara toku na ko wulo ma... Ori je asiwaju tori ohun ni olohun fise olutosona eda nile aiye...ti ori eni bagba abode, isemi eniyan yen mawa ninu wahala ati idamun ni.. Tori re ni agbodo fi mojuto eleda wa tabi iseda wa, tori re ni awon baba wa fi pataki ori.. Awon baba wa amaso pe (ori ni apesin, ori ni gbani, orimi matakomi, orimi magba abode) Adura ti awon baba wa ma nse Nipa ori kise kekere tori iseda eniyan se pataki ninu aiye.. KINI ANPENI ORI BIBO.. Ori bibo je ona ti awon baba wa ma ngba lati lefi be ori (head) tabi se etutu ori.. Ni asiko ti nkan bale ma eda, ti atije ati mu ba nira tabi ti orire ba gba abode.. Opolopo eniyan ni ori re le pupo, tosi ye kioma bo orire lorekore tori iseda re le, sugbon opolopo eniyan koma iru iseda ti ohun nlo debi toma mape oye ki ...