ASIRI NLA TOWA LARI AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON

 

 ASIRI NLA TOWA LARIN AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON 



1. OMI ATI OMI


Ibeere kan timo ma nbi awon onirawo kan na toba fe ferawon nipe, Shey won setan lati se suuru fun arawon.... Tori ija amawaye larin won, kosi biwon sefese ti won ba nja ni gbogbo igba..... Nkan lema lo dede fun... Sugbon tiwon bagbo arawon y,tiwon sin ran arawon lowo Lori biwon ose mani ilosiwaju..... Ibagbe won ma roru.. Osima mu ire topo wani idile won.  


2 OMI ATI ERUPE


Won le fe arawon,won sile Jo da ise po, tiwon kobati je ewo tabi ki enikan mase sina.sugbon iyepe ni ibase yi ma rorun fun julo.


3 OMI ATI INA


 omi ni pa oro Ina..... Gbogbo wa lama pe irawo omi ati Ina kobarawon mun, beni kosi irawo ina ati omi kobarawon mun sugbon irawo ina kan wa to anfani lati fe irawo omi but oni side effects re o.  


 iseda ina kan wa tojewipe ibasepo todan moran wa laarin oun ati omi koda won le da ise po beni won le fe arawon , sugbon tiwon je ewo ati wonko tele ofin ati ilana irawo won... Wonma pada ja ajatuka ni o


 

4_ OMI ATI AFEFE


 won le fe arawon gegebi oko ati aya, won lejo se ore beni won le da ise po... irawo afefe ni lati mase itoju irawo omi tori ilosiwaju tie, leyin gbogbo eleyi ibagbe powon madun lopin igba tiwan ba tele ofin irawo ati opolopo saara sise leyin roma irawo won, sugbon won o tete mari asise arawon, afefe toma fe si omi,omi yosi ma fe kiri,omi loma gbadun pupo ju ninu ibasepo won


5_ ERUPE ATI ERUPE


ajogbe iyepe ati iyepe_ajogbe won Dara pupo,oore si man be ninu ibasepo won, tiwon bajo da ise po tabi fe arawon tabi mu arawon lore,koni si wahala tabi inira fun won rara,ayafi ti enikan ba wọ won larin toda ija siwon ni arin won le tuka, be sini adamo 


6_ INA ATI ERUPE


ajogbe ina ati iyepe_ opolopo awon ojogbon ni kofara mo ibasepo won, nitori wahala ati inira ti ina yio ma fun iyepe ti kosi ni leke si ita,sugbon won le fe arawon, won le Jo da ise po beni won le mu arawon lore, sugbon  ina yio pada re iyepe je toripe iyepe koni fe ija beni kosi nife wahala.. 


Inira tolagbara ni awon iyepe ama ri lodo ina,gbogbo ise ti iyepe base ina ni yio fi sin, won yo pada tuka ni ayafi ti iyepe bafi ara da iya yen loku.

Etc... 


Aoma so iyoku ni ijomi tori oro ti akole sotan ni...mogbadura pe gbogbo awa tia wo oju olohun fun oko tabi iyawo..... Eoni gbe egu elegu o... 


NOTICE 


Opolopo lofe ma asiri irawo re sugbon kole fefi owo wa mima... Nkan tio yewa nipe owo lafin ra otito... 


Awon tioma so isokuso funyin laigba kobo lowo yin le nwa kiri... Hhhun olohun koni shiwa lona... 


Eniyan toba setan lati wa ojutu si oro aiye re, koni ko iyekiye to ma na... 


Fun iwo tioba setan lati ma asiri irawo re, akosejaiye,spiritual consultation lori isoro kan sikeji, ninu igbeyawo, lenu ise, onilo imaran lori nkan nkan....message me through this link 🔗 https://www.facebook.com/profile.php?id=100093315740015


.

Comments

Popular posts from this blog

IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)

ÀJÉ (WEALTH)

ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)