IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)
Nje iwo tie se iwadi kankan kio to ma ni ibalopo (s*x) pelu eni tio ndate lowo... Opolopo yin kan ni ibalopo pelu eniyan toba pade tabi towu e, nje iwo ma iru irawo ti eniyan yen nlo tabi iru eniyan toje kioto ma ni nkan papo pelu re, opolopo ogun aini ilosiwaju to nja elomiran... Kise ogun aiye tabi ogun idile bikise pe afowofa lofi koba arare..
Ibalopo lasan gan ole pa kadara eniyan da si aburu..
Gbogbo irawo loni irawo totako tie sugbon ikan ju ikan lo, gbogbo irawo ni kofara ma sina sise (adultery) sugbon elomiran mu ni igbadun, sina sise kun nkan ti opolopo elomi kofi ni ilosiwaju ninu irin ajo aiye re...
tori kosi bi wase mase sina kiri ti oni ni ibalopo pelu eniyan ti kadara irawo re tako tie.. Odeni ma tori nkan towu e lo nse.
Gbogbo nkan koni ogun sise... Akiesi ati ima nipa arare na se pataki ...
KINI AWON NKAN TI AMA NWO KIATOLE SOPE AWON IRAWO YI BARAWON MU DADA...
Awon nkan meta kan wa tia gbodo wo kato sope irin ajo won papo lati ferawon gege bi ololufe meji
1)IFE (LOVE)
Se ife wa larin irawo mejeji yi, se won ma feran arawon ti won ba tiferawon sile tan.... Tori nibi kiwon mari asise arawon ni wahala tima nbere ninu igbeyawo, Sugbon ti ife gidi bawa larin won... Won ma gba asise arawon... Won osile maran arawon lowo lopin igba ti ife bati wa larin won....
2)IWA ATI ISESI ARAWON (AFFINITY)
Se won nife si iwa ati isesi arawon, se iwawon barawon mu lati jo gbe papo, se won feran imura arawon, se won rewa (beauty) loju arawon..
Opolopo idile miran tidaru latari pe wonkoma iwa ati isesi arawon kiwon to ferawon sile, lafi ni kie study eniyan te nbarin dada kie to tesiwaju ninu irin ajo ife yin.. Iwa elomiran buru gan debi pe kose bagbe ile gege bi ololufe..
Koda ti ife bawa larin yin, ife lesalo nigba ti okan re bako awon iwa ati isesi toba bade lodo ololufe re...
3) SE KODARA IRAWO EYIN MEJEJI PAPO (COMPLIMENTARITY)
Gbogbo irawo loni awon spirits to nba sise, gbogbo irawo koni awon spirits won lebarawon sise papo tori awon spirits irawo kan toko awon irawo miran..
Tori re ni afi ma nsope komase (don't) awon nkan totako irawo re, awon spirits to nba esise nikofe awon nkan yen, awon spirits yi lo ndari irin ajo aiye re.... Tori re ni asiri fiwa labe irawo letile fima awon nkan ti spirits re fe ati awon kan tikofe..
Ti kodara irawo meji koba barawon mu awon nkan tio masele siwon niyi(ilosiwaju lema si larin won, ikorira lema waiye, ija gbigbona, kiwon maso asise arawon, ki ilosiwaju ma deba enikan ki enikeji sima ri ijakule) etc...
Spirit irawo miran kobarawon mu rara sugbon ife wa larin won besi ni iwa ati ise won barawon mu... Awon nkan wonyi lomu iyapa enu(contradiction) waiye lori compatibility irawo wiwo lorisirisi...
GEGE BI APEERE(SAMPLE)
won le so fun e pe irawo afefe ati omi kobarawon mu...
Kotun losi odo elomiran kotun sope obarawon mu... Setiripe iyapa enu tiwa nibe
Gbogbo awon Kini yi loni ofin tode won labe asiri irawo...
Tori re ni mofise iwe (PDF) asiri irawo fun eniyan toba nife si.. Kio message mi privately..
Tiwon baso fun e pe irawo erupe ati afefe koba arawon mu.... Oni reasons
Tori osese kojepe ife (love) nikan loma wa ni arin won tiko ni si awon nkan toku timo daruko yen nibe...
Osile sese kojepe spirit won barawon mu kojepe koni si ife gidi larin awon...
Sugbon kiatole sope irawo yen dara lati fe arawon, ayafi ti awon nkan meta yi bape sibe..
Compatibility irawo nkan tokosi nu po ti miole so tan nisin... Ama mu awon asiri yen wa die die..
Iwo tio bafe ma nipa irawo re ati itosona lori compatibility lori ololufe re... Message mi privately
AKIESI PATAKI
Opolopo wa gbagbe pe irawo mejila (12) lani, isori(parts) won lopin si merin (4)
tiama si Irawo OMI, AFEFE, INA, ERUPE....
Sugbon opolopo wa akoma pe asiri to connect irawo omi meteta papo wa nipa ti ibasewon (compatibility)
Besini awon irawo toku na gege bi afefe meteta ati ina meteta pelu erupe na meteta...
Kiato ma wa connect won ma arawon bi apeere (omi +erupe)
(Afefe +ina) (omi +afefe) etc....
Gbogbo won pata loni asiri tosowon po nipa ti ibasepo (compatibility)..
Compatibility awon irawo miran dara pupo (70% 80% 90%)
Besini awon irawo miran wa todara die (40% 50% 55% 60%)
Awon imi kodara rara (10% 20% 25%)
Mokan fi awon per centage yen wonfunyin kiole bayeyin dada ni....
Comments
Post a Comment