OGUN ATI EGUN IDILE
OGUN ATI EGUN IDILE
púpọ eda níí oun koju awọn isoro wọnyii sugbọn niwọnba igba tii kobati dake lori oro aye e ti òde ti ṣe awa ri ara-re ọlọhun yóò mú ọ kúrú ninu oko aṣalẹ.
OGUN IDILE:- ma nje ki eyan walaye bii alaise ọpọ loyeki oti gaju bi otiwa lọ ṣugbọn *OGUN IDILE* tii ba tie jẹ besini bii kobasora atidide iru enibe yoo fẹ mú inira daani ejeki agbadura gidigan kasi sumon ọlọhun ọba kii asimase jékí igbiyanju wa dúró
Nje iwọ mọ pé Ogun idile je At'okun ifaseyin amubo ohùn réré sinu aiye ẹda
Orisirisi ona níí ogun idile ma ùn gba wọ inú àiyé ẹda ènìyàn
gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;
*ILÉ ỌDÚN*
Ile odun nii elomi lo tii WÀHÁLÀ fi wọnú Aiye
*OWÓ*
Owó nii elomiran fun awọn ara ilu ee tabi awọn agbolé ( family compounds) nii WAHALA fi bẹ silẹ ninu Aye é ki elédùmarè mase jeki abosi ọwọ kii Olohun siju Anu wowa.
ÀPẸẸRẸ LORI OGUN IDILE
*Ogun idile kii ùn jeki eniti oun wa ọkọ ríi ọkọ fẹ besini kii jẹ́ kii ọkunrin ríi aya fẹ
Ogun idile asitun mada oko ati aya laamu tikoni si ilosiwaju
*Opolopo graduate nii owalaye bii alaise bii gbogbo eyan barii ise oun ko niri iṣẹ ọjọ ti orire RẸ bafe tẹ lọwọ Aisan tabi ìṣòro kan yíò da duro sile
*Ounje oju orun nii gbogbo igba eleyi nii oluranlowo fún ijakule Orire nitori pe gbogbo eniti irú nkan báyìí ba ùn ṣele si wọn kìí tete tẹsiwaju ninu irin àjò ayé wọn
*Owo gbigba loju orun nii gbogbo igba iru nkan wọn yìí gbese ati oda owo nii oun fa sinu Aye ẹda eniyan
*Kii Eda maafii oju ko owu Alantakun nii gbogbo igba
Tabi kii alantakun ma ta owu di Onitoun loju nii gbogbo igba
* Biba obinrin tabi OKUNRIN nii IBALOPO SEX loju orun nii gbogbo igba.
Mogbaa ni dura fún gbogbo iwo ti oba bami share post yi wipe ki inira di oun igbagbe ninu aye re pẹlu aṣẹ edumare. Amin.
Omo iyami ma dake ma duro masun Lori oro aiye re.Follow us on this page https://www.facebook.com/profile.php?id=100093315740015
Comments
Post a Comment