OFA AIYE

              OFA AIYE


Ọpọlọpọ ènìyàn maun gbó ti wọn maun dàrúkó ọfà súngbon wọn kò mọ ìtumò rẹ dáadá ati iye ona ti ofa pinsi


Kini anpeni ofa atiwipe ona melo ni ofa pinsi bawoni awon ika eniyan Se ma nta eniyan ni ofa,  ema bami kalo... 


Awon ofa aiye yi pinsi erisirisi ona 👇


Ofa idaamu

Ofa aisan wa

Ofa iku wa 

Ofa ise (poverty) wa etc... 


Ofa tita ma eniyan da gege bi asasi to gbona gidigan tosepe eniyan tiwon ran asasi yen si nipase ofa tita..... Anu olohun nikan ati igbinyanju to lagbara ni kofini ba onitohun. 


OFA IKU


biwon bafe pa eniyan lojiji ofa iku tiwon ma ransi eyan yi.... Idini yi ti elomi ma nfi ku lojiji laisepe otire fun ojopipe iru eniyan be lema po eje lenu lojiji tabi kio pariwo lati oju orun jasi aiye, ojo ti ofa na baba eniyan nani oluware ofi aiye sile. 


OFA IDAMU

bi awon ika bafe damu eda, iru ofa yi ni won ma nta fun eniyan.... Gbogbo nkan ti oba nse laye re.... Yio ma damu nih.... Gbogbo adawole re asan nio ma jasi, iru oni tohun yiowa dabi alaimase lawujo.. Kosi iru ise igbinyanju tolese, koni sise àyàfi tioba mu ofa na kuro lara... 


OFA AISAN

Ki olohun maje kia ko agbako ofa aisan, tori won oniri nkan to nse enina.... Wonkan ma fi ogun orififo wo arariro nih...... Kabiesi olodumare, ti olohun bafe fi iya je eniyan yio ni ki ofa aiye koba oni tohun, inira ati idanu ni enina máfí lo igbese aiye re toku àyàfi ti won ba rí ofa na mu kuro larare, 

Ofa yi ama pa eniyan tiwon koba ri mukuro lara enina... Ojo tio bajade laiye ni ofa yen makuro lara


OFA ISE (POVERTY)


Iru ofa yi lagbara debipe.... Gbogbo ona ni Anu ofima jina si oni tohun... Gbogbo oore niyio ma jinasi iru eniyan be, bio ma se business toye kio rí ere repete, yio sort  nibe nih. 

Bio ba lo ise osole abi awure Anu, koni sise kankan.... Tiobatun wasise 

Tobaye kio rí 1million.. Boya 10,000 ni yio rí 

leyi toje pe boya 50k lofi se ise yen toye kiori 1m owa rí 10k..... Se ojere ni abi o sort.. 

Bi olowo kan bafe sanu awon eniyan... Koda kiowani waju, wonkoni rinari debipe wonma sanu re.. Aiye ama fi iru ofa yi bo ogo eniyan male (tikoni rí ogore lo) 


Awon ona ti awon ika eniyan ma nfin damu ogo eniyan niyi. 


ti ofa aiye bamu eniyan... Koni ogun àyàfi kiemu ofa yen kuro (ero ofa) ise toni AGBÁRÁ pupo nih ise yi 


Ti eniyan baba olooto ati alagbara eniyan togbo Sasa toni asiri na lowo pade... Ni eniyan filebo ninu wahala yi... Tori ofa yi lelo aimoye odun lara eniyan tojepe odi ojo iku kioto jade kuro lara oni tohun... 


Madake lori Oro aiye re tori awon to nlepa re kodake lori oro re, maduro lori oro aiye re tori awon to nle e koduro... 



FUN IWADI LORI IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE, CONSULTATION LORI ISORO KAN SIKEJI PELU ONA ABAYO, SPIRITUAL WORK LORI AWON NKAN TIMODARU SI OKE YI...MESSAGE ME PRIVATELYhttps://www.facebook.com/profile.php?id=100093315740015

Comments

Popular posts from this blog

IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)

ÀJÉ (WEALTH)

ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)