OKO ATI AYA ORUN


OKO ATI AYA ORUN





Gbogbo emi eniyan towa laiye loni... Won ni ibi tiwon tiwa... Awon emi kan wa lati ara eda alagbara miran bi ebora, iwin, awon alujannu..  

Gbogbo eniyan toba ku losi ni ibi ti emi na nlo... 

Asiri topamo si odo olohun leleyi.. Sugbon ninu imo tofun awa eniyan la fin soro yi.. 


Bi ase nse emi nile aiye yi nani... Awon oniranran emi na nse tiwon lagbede meji aiye ati orun 

Awon emi totiku lojo toti pe ati awon eyi tosese ku gege bi awon emi (eniyan, alujannu, ebora, etc..) 

Gbogbo awon emi yi na nse aiye miran nibi ti olohun ma nko awon emi si.. Awon na ama lo igbese aiye gege bi eda alaye nibe... Won ama feranwon bi loko laya.. Wonsi ni EGBE lerisirisi gege bi awa eniyan na sema ndarapo ma egbe e. g egbe olorin, egbe oni film, egbe alaso, egbe  iya laje etc... 

Bi awon na se ni egbe lorun niyen... Ni erisirisi egbe ti akole ma daruko... 


Gege bimose so tele pe awon emi tia nso yi (ninu alujannu, eniyan, awon emi oniranran ti olohun ma) 


Ti olohun basetan lati mu emikan wasi ile aiye wa yi... Olohun mawa mu emikan si ara eniyan to nbowasi ile aiye kekebi omo tuntun... Oleje ninu emi alujannu abi emi eniyan gangan abi awon emi oniranran toku ni olohun fisi ara omo tuntun... 


Ti omo na bawasi aiye.. To baje okunrin tosi ni iyawo nibi toti wa lohun.... Iyawo na mama wa yojusi nigbogbo igba... Won asi mani ibalopo lopolopo igba.. Ti emikan bati waiye..  koni ma pe ohun tinlo isemi kan tele tori olugbagbe ni olohun da omo eniyan.... Idi niyi ti awon emi yi sema nwa ba ololufe won ni ajose po..... Bose ma sele pelu obinrin toba waiye ti ohun na ni ololufe lorun... 


Won amafi oko orun abi aya orun se eniyan ooo... Gege bi adanwo, won ma ran asasi yen si enina. 

Alujannu gangan nio wa lati inu Igbo, tiosi mawa ba onitohun lajosepo .... Oropo labe topic yi ejeki ntesiwaju ni ojo mi 


               OBINRIN


Obinrin tii oko orun ba unda laamu gbogbo igba nii yio ma la Ala ibalopo loju orun iruwon kii untete bimo.

Beesini bii wonba nii oko oseese kii ise okowon Mase tesiwaju nitoripe OKO orun amabinu sii oko Aye 

Kiitun se iye nikan gbogbo Owo tii iyawo ba ntu Joo latifise ikan rere asan Lori Asan nii ayafii kii ogbiyanju lati bo ninu wahala yii 


         IPADE OKO ORUN


Bii eniti obani oko orun baa unsaba ma unrin lorita meta daada oko ee amapade ee nibe besini Ifaseyin nii gbogbo ikan bayii ma unfa sinu aye oko tii obagbe iru obinrin bayii sile


Enitio ni oko orun yi ma nsaba feran latima sun sinu okunkun... Leyi tosi ma bawon laiye je sini 


Oko Orun ma npade iyawo ee nii ojo THURSDAY NINU Oja (market) kii olohun masejeki Asirin layewa abi orita meta 


  AWON APERE  TI OKO ORUN BA NDA ENIYAN LAAMU


Okunrin tii oba ma n fi ara ko owu alantakun daada nitoripe ijakule nii gbogbo igba nii oma nsaba waye fun iruwon... Osese koje ipe oko orun tabi aya orun ndamu iru eniyan be.. 


eniyan yi  ama Saba maa lala ibalopo loju orun tii asi maa gbadun ee ju tii oju ayelo.


Iruwon kii nsaba tete rii omo bii loju aye sugbon Inu egbe wonti bimo Repete fun oko orun idi niyi tii won fii maunso fun obiinrin imiran pe oti bimo daada tii asima jiyan pe oun kobimo rii

 ife.


Wonkii nsaba maa nfe kii isoro won kuro lara won.nitoripe OKO orun kii unfe fii iyawo ee sile besini opolopo igba nii Oro won kii un ye awon naa won osini ka oro ayewan kun debiti won awa ona abayo si koda tiwan bani owo lati Se Sara tabi igbinyanju ti oma yowan kuro ninu isoro yi ibomi ni won ma na owo yi si


               


Wahala nla nifun okunrin Tii obani Aya orun Nitoripe kowopo ninu awon okunrin Tii Oni aya orun sugbon eyii tii obani kii nsaba ma nse Aseyori pelu Awon Obinrin tii obanfe 

Ija Loni ijalola nii, kii unse ejo oun naa bii kii unsepe Awon isoro Aye ee nii.


            ONAA LATI MO OKUNRIN TI AYA ORUN UNDA LAAMU


Iru Awon enibayii konisi ilosiwaju kankan funwon. Yala nibi ise tabi Inu Ile 


Iruwon kii saba ma unkonu sii obinrin nitoripe Eru ma nbawon.


Iruwon ma unsaba ma un  masturbate dipo  kii won nii Ibalopo (sex ) pelu obinrin  nitoripe ikanyii ma undun mowon gan 


Iruwon kii unsaba gbe nkan rere see laye konisi Owo 💴 besini konibimo awadabi ejo tokoja  Lori Apata


         MAJEMU TII PUPO NINU ENITI OKO ORUN UNDA LAAMU MA UNDA FUN OKOWON LORUN


Elomi   Ma unfi ọjọ́ ikùn lè ( labouring day) búra wipe ojo yii nii oun yio pada 

 

Elo miran ma unfii ojo IGBEYAWO( wedding day) bura wipe ojo yii nii oun yio pada


Elomi ma sope tio oun bati pe iye odun bayi nile aiye ohun pada bo 

 

  Ogun kii un tete sise Lara eniti Aisan yii ba ndalamu nitoripe awon ololufe won kii unfeki won fii awon sile Adura ATI igbiyanju topeye nii afii nbo lowo OKO ATI AYA ORUN.


Mo gba ladura fun gbogbo eniti oko ati aya orun nda lamu,wipe Eledumare a yo yin  kuro ninu isoro Na toriwipe 

Oun Aburu gba nii Awon ikan yin ma nfa sinu Aye Eda.


Iwo tobafe ra iwe Asiri irawo mi... Owa Nile fun tita o, fun iwadi lori isorokan abiidojuko lori lenu ise, ninu igbeyamo etc.. Message me privately on this page https://www.facebook.com/profile.php?id=100093315740015

.

Comments