AJE ARA IRAWO KOKAN ATI IBI TI AJE NA MA NWA....

 AJE ARA IRAWO KOKAN ATI IBI TI AJE NA MA NWA.... 




Gbogbo irawo kokan loni aje tie... Ode ni ibi toma nwa lara eniyan... Yatosi awon omo elegbe. 


Awon irawo kan wa tia masi irawo aje, tojepe dandan ni owo lodowon (wongbodo lowo laiye won ni ona irorun)... Sugbon kadara  leyi lori irawo won ti awon abateni je bafi owo ba ogo aiye won, 

Olohun wa beni eyan na wa.... Olohun lofun won lagbara lati dari aiye bose wuwon.... 


Laisi wahala awon agbalagba ati ogun aiye... Awon irawo yi ma nri ti aje se gan.. Tori aje yen lonje oba irawo won.... Ama so oro yi ni ojo mi tori topic kan ni loto.... 


EJE KIN PADA SI ORI AJE ARA IRAWO KOKAN..... 


1) AJE ARA IRAWO INA 


Irawo ina lama si irawo imole to ntasi nu okunkun, irawo nla ti irawo ina je.... Adari aiye pelu imo ati opolo niwon..... Akoda onirawo ina latiwa je ero eyin tori eniwaju niwon... Onirawo yi tikoba ri ilosiwaju ninu aiye re..... Oni reason 


Afowofa, ewo jije, ogun aiye tabi ogun idile, aimo ni imo nipa irawo re ati akosejaye re... Gbogbo nkan wonyi loma ndina ilosiwaju fun irawo ina.. 


Papa julo Afowofa.... Ninu afowofa ni kiwon maase sina... Sina adultery yara pa ogo irawo ina... 

Aje ara irawo ina wani abe ahon (tongue) re... Lofi jepe gbogbo igba ti onirawo ina ba nsepe fun eniyan tabi kioma ba awon eniyan ija ni ore ma nsaba bo lowo won... Eleyi je okan ninu okunfa aini ilosiwaju... Aje kofe ija ati epe, Ibinu ati ki eyan male gba egbin mara... 


2)AJE ARA IRAWO OMI 


Ololufe aiye ni irawo yi je.... Aiye ama gba tiwon ni ibi tiwon bade, olorire eda, olohun fun won ni asiri emi (spiritual power) , ONIBINU ni opolopo won, emi awon apakan ninu irawo yi kokin gun... Iku ojiji ma npawon tori tori ewu nla towa ninu irawo won ni, iku ati atunbi(death and rebirth)  wa ninu irawo abawa ye won, oma nse ni lanu funwon timoba ranti ewu nla yi... 

MOMA SORO LORI EWU NLA TOWA FUN IRAWO KOKAN... SUGBON KISE OJO ENI... 


  opolopo onirawo omi koma ofin tode irawo ati akosejaye won ni won fi ma si ese gbe laro ojo aiye won.... Ni won fi ma nsaba jiya gan kiwon to jana, opolopo won gan won okin ri ebun (talent) won lo tori irin ajo aiye won tidaru.... Sugbon onirawo omi toba ma ofin tode oro igbese aiye re.... Yio tete ri ogo re lo, 


Aje ara irawo omi wani owo (hand) won, Lofi jepe gbogbo igba ti apere kan ba nhan siwon nipa boya won Mari owo nla kan tabi ore kan nbo funwon ni owo (hand) ama hun won.. 

Aje ama kilo funwon nigbami tiwon ba nse nkan tikoto latise.. Sugbon opolopo won kokin sakiesi re.... Mase ja tabi kio mabinu si awon eniyan.... Gbiyan ju kioma ran awon eniyan lowo pelu nkan to ba wa ni ikapa re... Tori ki ole tete ri anu olohun lori oro aiye ni, irawo yi ni ewu ninu pupo... 


3)AJE ARA IRAWO ERUPE 


Irawo awon agbalagba 🙏.... Awon alagbara omo pelu spiritual power loma nsaba jade ninu irawo yi, awon omo ologo didan, apakan ninu irawo yi loye kia mape ni (imole)  awon tio ba nbi iru omo yen lole royin funwa... 

apakan irawo yi si ni ebun (gift) emigigun, 

Awon apakan asije oba (king) tori ori ade ni awon ipin irawo yen..... 

Irawo yi yato gedegede si awon irawo toku.... Tori ogun okin sise lara opolopo won..... Mo tin so nkan toba ipin irawo erupe mu.... Etc.. 


Aje ara irawo erupe wani gigise re mejeji.. Lofijepe irin oru (late traveling) koba kadara won mu, tori akoba ni fun irawo won ati aje arawon, irawo erupe kogbodo masun si ilele (ground) tori akoba ni fun aje arawon.... Etc.. 


4)AJE ARA IRAWO AFEFE  


Arin irin ajo aiye, oni mimo aiye, ojogbon eniyan, celebrities ma npo ninu won, irawo lile ni irawo yi.. Ori won sima nle, lafi ni kiwon ma bo ori won dada.... Ogun okin sise lara apakan ninu irawo yi.... Awon agbalagba omo na po ninu irawo yi 


Opolopo won ama ni idojuko ati isoro topo gan Debi ipe aiye afe suwon... Sugbon tiwon base gun pere... Aiye afi olawon toro ni... Bi ola  ati okiki won ase to.. Sugbon opolopo won koma oju ona.


Aje irawo afefe wani owo osi re tori re ni owo fi ma hun opolopo won.... Owo hunhun ni itumo topo sugbon oni kise ojo oro yen...  


NOTE

Egbe fun irawo afefe ati omi je anfani ati ewu fun won..... Anfani lati ni ogo, ola laiye fun eniyan toba ma bi ase ma ntoju egbe tikosi si atako pelu ohun ati egbe re.... Awon ika aiye ama ko eyin eyan ati egbere sirawon tori won mape ti awon egbe koba tise tie ma... Koni rojutu aiye re.... Won okuku fe ki roju tu aye re na tete... 


Kosi irawo ti olohun kose fun sugbon oju arawon lo... Tori idi eleyi ni wonfi ma nkoju isoro ati wahala jurawon lo.... Gbogbo wa loye kia ni owo lowo sugbon idi tofa ise (poverty) ati awon isoro toku... Gbogbo re ni reasons topo tikose sotan...




 AMA SORO LORI AWON IDI TI OLOGO OMO FI MA NJIYA ATI WAHALA...


Oro aiye wa gba amojuto.... Kiale tete ri ona lo 

Wahala ati idamu kise omo iya ara... Besini nkan ti otare fe fun e niyen... Iwo loni gbafun won. 


Se iwadi lori irawo ati akosejaye re... Sise igbiyanju leyi toba kadara re fun ki Adura re letete gba... Tori awon to nle e wonkoduro... Iwo na masare lori oro aiye ni kiole tete mu oke.... 


fun iwadi irawo ati akosejaye re, tabi iwo fe wadi imo, atuse lori isoro aiye re, ninu igbeyawo, lenu ise,(spiritual problem and healing).. Message me privately on my page through this link 🔗 https://www.facebook.com/profile.php?id=100093315740015&mibextid=ZbWKwL



OLOHUN LONI GBOGBO RE

Comments

Popular posts from this blog

IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)

ÀJÉ (WEALTH)

ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)