ELEGBE ORUN
ELEGBE ORUN
70% eniyan towani aiye loni níwòn ni egbe sugbon awon tikoma pe awon ni egbe lopoju ninu wa, egbe orun je nkan topama koda egbe imi koni han ninu iwadi, akan Mari pe oni egbe ni sugbon iru egbe toni koni han, asiri topamo si odo olohun ni eleyi...
KINI ANPE NI EGBE ORUN GAN
Bimose salaye lori oko orun ati aya run pe gbogbo eniti oun gbé nile aiye loni ibi ti emi won tiwa, opolopo emi lowa lati agbede meji aiye ati orun...
Ibe ni gbogbo emi ti olohun da wa, ninu emi tiowa nibe (emi eniyan, emi alujannu, emi awon eda alagbara miran) gbogbo awon emi ni yio ma lo igbese aiye miran nibe.....
Bi ase nse emi nile aiye yi nani... Awon oniranran emi na nse tiwon lagbede meji aiye ati orun
Awon emi totiku lojo toti pe ati awon eyi tosese ku gege bi awon emi (eniyan, alujannu, ebora, etc..)
Gbogbo awon emi yi na nse aiye miran nibi ti olohun ma nko awon emi si.. Awon na ama lo igbese aiye gege bi eda alaye nibe... Won ama feranwon bi loko laya.. Wonsi ni EGBE lerisirisi gege bi awa eniyan na sema ndarapo ma egbe e. g egbe olorin, egbe oni film, egbe alaso, egbe iya laje etc...
Bi awon na se ni egbe lorun niyen... Ni erisirisi egbe ti akole ma daruko...
Gege bimose so tele pe awon emi tia nso yi (ninu alujannu, eniyan, awon emi oniranran ti olohun ma)
Ti olohun basetan lati mu emikan wasi ile aiye wa yi... Olohun mawa pase emi si ara eniyan to nbowasi ile aiye kekebi omo tuntun... Oleje ninu emi alujannu abi emi eniyan gangan abi awon emi oniranran toku ni olohun fisi ara omo tuntun...
Ti omo na bawasi aiye.. tosi ni egbe nibi toti wa lohun.... awon egbe re mama wa yojusi nigbogbo igba...koni ma pe ohun tinlo isemi kan tele tori olugbagbe ni olohun da omo eniyan.... Awon egbe re ma se afeku re... Idi niyi ti awon emi yi sema nwa ba ni opolopo gba ..... Bose ma sele niyen....
Erisirisi egbe lowa ti opolopo koma.. Omo omi lo common,koda elomi koma iru egbe ti ohunwa... Ode npe ara re ni omo omi 😂
Omo omi lodaran lowo yin😂
Gbogbo awon egbe yi loni agbara tiwon, anfani tiwon lese fun omo egbe won ati fun idile toti jade
EJE KIA MU ENUBA DIE NINU AWON EGBE ORUN
EMERE OMI :-omo omi ni awon wonyi, inu omi ni ipade won, won si lagbara pupo ju awon egbe toku lo, aje (wealth) de wa Lara won pupo, okunrin toba nfe won marishe gan etc....
Ninu egbe emere omi ni atiri awon oruko egbe bi... Iranse aje (wealth), iranse omi, omi anu, igi aje (wealth), omo omi, etc...
-EMERE OFURUFU :-oju orun(atmosphere) ni ipade won, wonsi lagbara pupo, opolopo awon omo elegbe yi loma nsaba rirawon ninu afefe lori oke, awon omo elegbe yi wopo ninu irawo afefe dada.
EMERE ORI AKITAN:- ori akitan ni ipade won, awon wonyi ni wonpe ni emere alakisa, wonsi ni agbara pupo, ama agbako ni awon egbe yi je tori oko toba fewon yio matosi kosi bi okunrin na sele ma lo nkan igbinyan ju to, koda bi okunrin ba bawon ni ajosepo lasan bad luck lomari.
Emere inu igi ogede :-awon egbe yi kokin ni emi idarijin ti eyan basewon, inu igi ogede ni ipade won tima waye, okunrin toba se obinrin won, won oni darijin, won de ma fi iyaje okunrin na, biwon se waburu toyi wonma ran eyan lowo, okunrin inu omo elegbe yi ma nsaba ni emi idari jin.
EGBE ALAROGBO (APATA) ;- awon emere inu apata (rock) ni awon wonyi
Awon alagbara omo ni awon omo inu egbe yi je, agbalagba omo niwon.
EGBE ASHIPA :-iru awon omo egbe yi ni won ma nya apata (stubbornness), opolopo won okin gboro si awon obiwon lenu rara, won ma pada di curtism, robber etc..
Sugbon eyi ti adua bagba lorie lo ma npada di jagunjagun bi soldier etc
Tori omo lile niwon.
EMERE INU IGI IROKO:- awon egbe inu igi ni won, awon alalujannu omo, inu igi ni ipade won, won ma n ni agbara gan etc....
Asiri po labe topic yi... Asiri tosi pama nih.. Sugbon ninu ti olohun fun awa eniyan lafin soro yi.....
NINU AWON IDOJUKO TI AWON OMO ELEGBE NI.
Promise and fail ma nda won lamu, amubo oko, oko orun, ibujoko, idojuko lenu ise etc...
NJE IWO MA IYATO TOWA LARI EMERE ATI OMO ELEGBE LASAN
COMING SOON 🔜
NOTICE:- E KIN FOLLOW PAGE YI LATI ENCOURAGE WA.... OYEKI PAGE YI TI GROW JUBAYI LO ABI PAGE YI KO DESERVE FOLLOW NIH? .... GBOGBO WA KAN KA CONTENTS LASAN NI... DAKUN LOBAMI FOLLOW PAGE YI NI KIAKIA BAYI
BI OSE NBAMI FOLLOW PAGE YI..... OGUN ISE (POVERTY) DI OUN IGBAGBE NINU AIYE RE
SE IWADI ORO AIYE ARARE KIOLE BO NINU ISORO
FUN IWADI LORI IRAWO RE TABI AKO SEJAIYE, SPIRITUAL CONSULTATION... MESSAGE ME PRIVATELY

Comments
Post a Comment