ASIRI TOWA LARIN IRAWO INA ATI ERUPE

 ASIRI TOWA LARIN IRAWO INA ATI ERUPE


Àwọn ènìyàn kan nii irawo ina kogbodo fẹ irawo erupẹ 


Bé sini awon eniyan kan nii won lè fẹ arawọn 


EJEKI ASORO NIPE IRAWO INÁ ATI ERUPẸ 


Njẹ iwọ mọ pé kii ùn se gbogbo ipin irawo yi nii won lè fẹ arawọn tabi da iṣẹ pọ nitori pe wahala amasele siwọn


Opolopo igba ni moti ma nsofun awon eyan pe... Irawo erupe ati irawo ina kogba ti arawon..... 

Inira ti irawo ina amafun erupe kise kekere, iyanje mapo, ti erupe na babinu, ija mawa di ija igboro, 


Kosi nkan tiwon lemase fun arawon ni tidada.. Bi alaima se nani,.... 


Ija ati wahala ni gbogbo igba.... Ayafi ti irawo erupe bale ni suuru gidigan.. Sugbon kosi bi erupe sele ni suuru to.... Irawo ina matan ni suuru nani 😂.... Ki olohun towa sona 🙏


AWON NKAN TIAMA SELE SI IRAWO ERUPE ATI INA TIWON BA FERAWON..... 


IRAWO INA TONKANYANRAN (ARIES) PELU IRAWO ERUPE FUNFUN (VIRGO)


ti irawo ina Aries bafe erupe funfun Osese ki gbogbo aje ara Virgo tiama si erupe funfun masise fun irawo ina tonkanyanran, irawo Virgo je irawo Toni aje Lara tori erupe odo (river) ni.. Omo omi sipo ninu irawo yi... 

irawo ina aries yi ni ore ofe pupo lati fe irawo pupo ninu irawo mejila tiani.. 


Ina tonkanyanran nii yóò ma pàṣẹ nitori ipin irawo yii kii gba fún ẹnikẹ́ni....irawo apase ni. 


Wonmagbadun arawon lopin igbati aje ara Virgo bati nsisefun Aries, agaga ti Virgo baloje omo omi, ayafi tiwon bani isoro ninu aiye won loku


Note : oda ti Aries baje okunrin ti Virgo sije obinrin... Equation balance niyen. 


ERUPE ERUKU (CAPRICORN) PELU IRAWO INA (ARIES) 


Ti irawo ina Aries ba fẹ erupẹ eruku carpricon won koni gbọ arawọn yé tii oba dii tii Olowo 💰 dé ....nkan okin saba lo dede fun iru idile yi..... Ayafi ti capricon bani aje lara tositun je omo omi nikan ni ifọkanbalẹ yio ma ṣẹlẹ siwọn.. 


IRAWO ERUPE AMO TAURUS PELU IRAWO INA ARIES


Bíi irawo ina aries ba fẹ irawo erupe Amo Taurus.. 

Kosi eniti yiò gbó ija won tiwon ba nife arawọn ṣugbọn nkan kekere nii yiò ma padà fa ìbínú larin won. Aries je olokan riru, ati onibinu... 

Beni Taurus je alagidi ati olorikunkun. 

Ti awon irawo yi ba ferawon tikosi wahala kankan, kadara kowonpo niyen... Tori olejepe ibikan nani wontijo wa lati orun... Irawo owo (money ) ati irawo ife (love) ni irawo Taurus... 


INÁ TONGBONA RÍRÍ ♌ LEO ATI IRAWO ERUPE TAURUS


Bíi irawo ina Leo yii ba fẹ erupẹ Amo Taurus 

konisi ilosiwaju funwon tori ayanmo irawo won kopapo.... Irawo erupe amo koni connection kankan pelu irawo Leo... 


IRAWO INA TONGBONA RIRI (LEO) PELU ERUPE ERUKU (CAPRICORN) 


Bíi irawo ina leo yii ba fẹ eruku Capricorn ifọkanbalẹ yio jina sinu idile won, tori ija nla amasele larin won 


IRAWO INA (LEO) PELU IRAWO ERUPE( VIRGO)  


Idamu yio ma ṣẹlẹ síi ọkọ tàbí iyawo tii Obaje ♍ VIRGO nitori pe Àjé 💰 tiò wa nii ara virgo yiò ma bínú síi irawo iná tongbona riri leo ... eyi sile fa wahala fún VIRGO


  *INÁ ÀTÙPÀ SAGGITARUS♐ ATI IRAWO CAPRICORN ♑️ 


Ti irawo ina atupa yii ba fẹ erupe eruku carpricon♑

Ilọsiwaju koni sii 

Iru awon idile yii ni kini akojọ leyin igbeyawo won 


INA ATUPA PELU ERUPE VIRGO ♍️ 


 Ti Irawo yi bafe erupe funfun ♍ VIRGO... Kabiesi eledumare 


Ipinya má sele siwọn gbẹyin nitori ko nisí agbọye funwon

Agaga tii iyawo bajẹ erupe funfun ♍ VIRGO on nii yiò ma bọ(feed) ọkọ. 


NOTE 

nje emape aditu kan waninu awon irawo totako arawon yi timo daruko si oke... Awon apakan waninu won tiwon le ferawon laisi ija tabi wahala larin won.... Iyen nipe ti awon mejeji baje omo omi... Osese kiwon gbati arawon, ti aje arawon sima barawon sise dada.... Nitori pe ibikan nani won tijade tise omo mi... 


Nkan ti awon aworawo ojo waju (psychic) ma nri niyi tiwon fima nsope kadara won barawon mun.... Sugbon kokin ye opolopo eniyan irawo ni won ma nwo... Misope irawo wiwo kise itosona o sugbon ti oro irawo batin tako (contradict) oro aiye yin... Kuku go spiritual 

Tori aditu loro yen feje niyen.. Bi irawo se nsise itosona ni akosejaiye nsise imonipa asiri ojo waju yin.. 


Psychic timo nsoro nipare yi ni ama nbayan wo gege bi spiritual consultation on spiritual problems, marriage, destiny etc....  


Ninu awon contents mih tonbo Lona ni mati maso 👇👇👇

NJE IRAWO MEJI LESISE FUN EYAN KAN... 

NJE IRAWO AWON OMO LESISE FUN AWON OBI WON... 

NJE OMO LEMALO IRAWO AWON OBIRE.... 

BAWONI IRAWO OKO SELE SISE FUN IYAWO.... BAWONI TI IYAWO SELESISE FUN OKO RE...... COMING SOON 🔜 ON THIS PAGE


Mo nfi gbogbo awon asiri yi lesita tori kole maje itosona fun opolopo idile tikoma nkan tonfa wahala leyin igbeyawo won.... Gbogbo eyin eyin tiefe irawo totako irawo yin (atuse wa) 

Atuse ibeni pe kie ma asiri irawo yin ofin ati ilana tode irawo eyin mejeji pelu Sara eyi toroma irawo yin... Kiesise lorire.. Adura yin magba. 


Mogba ladura fun gbogbo eniyan toba bami follow page mih tosi share post yi..... onilo ogore ninu sare  


             ✍️✍️✍️OBA IRAWO✍️✍️✍️


FUN IWADI IRAWO, SPIRITUAL CONSULTATION TABI ITOSONA LORI ORO AIYE RE, IGBEYAWO... MESSAGE  ME PRIVATELY (YOU CAN REACH US THROUGH  OUR PAGE )






Comments

Popular posts from this blog

IBASEPO AWON IRAWO(COMPATIBILITY OF STARS)

ÀJÉ (WEALTH)

ORI-BIBO.. (APPEASE YOUR CREATURE)