Posts

ASIRI NLA TOWA LARI AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON

   ASIRI NLA TOWA LARIN AWON IRAWO NIPA IBAGBEPO WON  1. OMI ATI OMI Ibeere kan timo ma nbi awon onirawo kan na toba fe ferawon nipe, Shey won setan lati se suuru fun arawon.... Tori ija amawaye larin won, kosi biwon sefese ti won ba nja ni gbogbo igba..... Nkan lema lo dede fun... Sugbon tiwon bagbo arawon y,tiwon sin ran arawon lowo Lori biwon ose mani ilosiwaju..... Ibagbe won ma roru.. Osima mu ire topo wani idile won.   2 OMI ATI ERUPE Won le fe arawon,won sile Jo da ise po, tiwon kobati je ewo tabi ki enikan mase sina.sugbon iyepe ni ibase yi ma rorun fun julo. 3 OMI ATI INA  omi ni pa oro Ina..... Gbogbo wa lama pe irawo omi ati Ina kobarawon mun, beni kosi irawo ina ati omi kobarawon mun sugbon irawo ina kan wa to anfani lati fe irawo omi but oni side effects re o.    iseda ina kan wa tojewipe ibasepo todan moran wa laarin oun ati omi koda won le da ise po beni won le fe arawon , sugbon tiwon je ewo ati wonko tele ofin ati ilana irawo...

OKO ATI AYA ORUN

Image
OKO ATI AYA ORUN Gbogbo emi eniyan towa laiye loni... Won ni ibi tiwon tiwa... Awon emi kan wa lati ara eda alagbara miran bi ebora, iwin, awon alujannu..   Gbogbo eniyan toba ku losi ni ibi ti emi na nlo...  Asiri topamo si odo olohun leleyi.. Sugbon ninu imo tofun awa eniyan la fin soro yi..  Bi ase nse emi nile aiye yi nani... Awon oniranran emi na nse tiwon lagbede meji aiye ati orun  Awon emi totiku lojo toti pe ati awon eyi tosese ku gege bi awon emi (eniyan, alujannu, ebora, etc..)  Gbogbo awon emi yi na nse aiye miran nibi ti olohun ma nko awon emi si.. Awon na ama lo igbese aiye gege bi eda alaye nibe... Won ama feranwon bi loko laya.. Wonsi ni EGBE lerisirisi gege bi awa eniyan na sema ndarapo ma egbe e. g egbe olorin, egbe oni film, egbe alaso, egbe  iya laje etc...  Bi awon na se ni egbe lorun niyen... Ni erisirisi egbe ti akole ma daruko...  Gege bimose so tele pe awon emi tia nso yi (ninu alujannu, eniyan, awon emi oniranran ti ...

OGUN ATI EGUN IDILE

 OGUN ATI EGUN IDILE  púpọ eda níí oun koju awọn isoro wọnyii sugbọn niwọnba igba tii kobati dake lori oro aye e ti òde ti ṣe awa ri ara-re ọlọhun yóò mú ọ kúrú ninu oko aṣalẹ. OGUN IDILE:- ma nje ki eyan walaye bii alaise ọpọ loyeki oti gaju bi otiwa lọ ṣugbọn  *OGUN IDILE* tii ba tie jẹ  besini bii kobasora atidide iru enibe yoo fẹ mú inira daani ejeki agbadura gidigan kasi sumon ọlọhun ọba kii asimase jékí igbiyanju wa dúró Nje iwọ mọ pé Ogun idile je At'okun ifaseyin amubo ohùn réré sinu aiye  ẹda   Orisirisi ona níí ogun idile ma ùn gba wọ inú àiyé ẹda ènìyàn  gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;                *ILÉ ỌDÚN*  Ile odun nii elomi lo tii WÀHÁLÀ fi wọnú Aiye                  *OWÓ*  Owó nii elomiran fun awọn ara ilu ee tabi awọn agbolé ( family compounds)  nii WAHALA  fi bẹ silẹ ninu Aye é ki elédùmarè mase jeki abosi ọwọ kii Olohun siju Anu wowa. ÀPẸ...

OFA AIYE

              OFA AIYE Ọpọlọpọ ènìyàn maun gbó ti wọn maun dàrúkó ọfà súngbon wọn kò mọ ìtumò rẹ dáadá ati iye ona ti ofa pinsi Kini anpeni ofa atiwipe ona melo ni ofa pinsi bawoni awon ika eniyan Se ma nta eniyan ni ofa,  ema bami kalo...  Awon ofa aiye yi pinsi erisirisi ona 👇 Ofa idaamu Ofa aisan wa Ofa iku wa  Ofa ise (poverty) wa etc...  Ofa tita ma eniyan da gege bi asasi to gbona gidigan tosepe eniyan tiwon ran asasi yen si nipase ofa tita..... Anu olohun nikan ati igbinyanju to lagbara ni kofini ba onitohun.  OFA IKU biwon bafe pa eniyan lojiji ofa iku tiwon ma ransi eyan yi.... Idini yi ti elomi ma nfi ku lojiji laisepe otire fun ojopipe iru eniyan be lema po eje lenu lojiji tabi kio pariwo lati oju orun jasi aiye, ojo ti ofa na baba eniyan nani oluware ofi aiye sile.  OFA IDAMU bi awon ika bafe damu eda, iru ofa yi ni won ma nta fun eniyan.... Gbogbo nkan ti oba nse laye re.... Yio ma damu nih.... Gbogbo adawole...

ÀJÉ (WEALTH)

Image
 ÀJÉ (WEALTH)   Aje olokun asoro di ayo, wafi ile mise ibugbe.... Se gbogbo wa nani ama  ewo aje? ,shey gbogbo wa lama itoju aje?.  Aje yi je nkan tio ma sise owo wafun eda eniyan, ti ogo eniyan sima tete buyo ise keke re owo nla, koda eniyan lema ni ise gidi kan lowo ti owo asima wole ni onakona, eniyan ti aje ba wa ni arare tikosi je ewo aje tabi awon ti ika eda kofi oju si lara debi tiwon madena lati ri aje re lo, iru eniyan be mama ri owo ni ona tiko ro rara... Iru won ni won ma ntete ni owo lowo... Ni owo toje owo nla.  Eniyan tio ba ri aje lo, koni damu laiye kio to ni owo. Àjé je nkan  pàtàkì tii kii kúrò lára ẹniyan niwọn bá igba tii ẹda bati tètè se iwadi irawo re ati akosejaiye kiole ma nkan toye komase...  nje iwoma pe aje ama kuro lara eyan tiosi fi eniyan sile patapata.  AWON ONA TI AJE (WEALTH) FI MA NKURO LARA ENIYAN 1) ti eyan koba se awari ara re debi tio ma ma awon nkan totako  irawo ati kádàrá re, tori gbogbo eda loni ...

ELEGBE ORUN

Image
 ELEGBE ORUN 70% eniyan towani aiye loni níwòn ni egbe sugbon awon tikoma pe awon ni egbe lopoju ninu wa, egbe orun je nkan topama koda egbe imi koni han ninu iwadi, akan Mari pe oni egbe ni sugbon iru egbe toni koni han, asiri topamo si odo olohun ni eleyi...          KINI ANPE NI EGBE ORUN GAN  Bimose salaye lori oko orun ati aya run pe gbogbo eniti oun gbé nile aiye loni ibi ti emi won tiwa, opolopo emi lowa lati agbede meji aiye ati orun...  Ibe ni gbogbo emi ti olohun da wa, ninu emi tiowa nibe (emi eniyan, emi alujannu, emi awon eda alagbara miran) gbogbo awon emi ni yio ma lo igbese aiye miran nibe.....  Bi ase nse emi nile aiye yi nani... Awon oniranran emi na nse tiwon lagbede meji aiye ati orun  Awon emi totiku lojo toti pe ati awon eyi tosese ku gege bi awon emi (eniyan, alujannu, ebora, etc..)  Gbogbo awon emi yi na nse aiye miran nibi ti olohun ma nko awon emi si.. Awon na ama lo igbese aiye gege bi eda alaye nibe... W...

IRAWO INA TOJE OMO ELEGBE

Image
 IRAWO INA TOJE OMO ELEGBE  Awon onirawo ina wo loma nsaba je omo elegbe?   IRAWO INA TONKANYANRAN (ARIES) omo omi  ma nsaba po ninu irawo yi, elomiran leje emere omi abi emere igbo.... Etc..  IRAWO INA TONGBONA RIRI (LEO) elegbe ma nsaba wa ninu irawo yi na sugbon ko po bi ti akoko yen... Omo elegbe bi iranse aje,emere igbo, emere igi ogede etc...  IRAWO INA ATUPA (SAGITTARIUS) bi irawo yi se kekere to, omo elegbe toba wa ninu irawo yi ma nburu gan, aje si ma nwa lara won dada, ama n saba ri elegbe omo bi omo omi anu, igi aje, emere igbo... Sugbon omo elegbe ko wopo ninu irawo yi..      APERE FUN IRAWO INA TOJE OMO OMI  Bii onirawo Ina Baje omo Omi die ninu  Awon  apere tio fima pe omo Omi todaju nii owun . ti eru ba ma nba ninu ile ti ayare yio si maja...  Bii kii Ori ee maadede dide lainidi....  Ki o  feran lati mada soro ni onni kan... Ero okan won ma nsaba wasi imuse lopolopo igba  Iruwon lokunrin ...