Posts

ELEGBE ORUN

Image
 ELEGBE ORUN 70% eniyan towani aiye loni níwòn ni egbe sugbon awon tikoma pe awon ni egbe lopoju ninu wa, egbe orun je nkan topama koda egbe imi koni han ninu iwadi, akan Mari pe oni egbe ni sugbon iru egbe toni koni han, asiri topamo si odo olohun ni eleyi...          KINI ANPE NI EGBE ORUN GAN  Bimose salaye lori oko orun ati aya run pe gbogbo eniti oun gbé nile aiye loni ibi ti emi won tiwa, opolopo emi lowa lati agbede meji aiye ati orun...  Ibe ni gbogbo emi ti olohun da wa, ninu emi tiowa nibe (emi eniyan, emi alujannu, emi awon eda alagbara miran) gbogbo awon emi ni yio ma lo igbese aiye miran nibe.....  Bi ase nse emi nile aiye yi nani... Awon oniranran emi na nse tiwon lagbede meji aiye ati orun  Awon emi totiku lojo toti pe ati awon eyi tosese ku gege bi awon emi (eniyan, alujannu, ebora, etc..)  Gbogbo awon emi yi na nse aiye miran nibi ti olohun ma nko awon emi si.. Awon na ama lo igbese aiye gege bi eda alaye nibe... W...

IRAWO INA TOJE OMO ELEGBE

Image
 IRAWO INA TOJE OMO ELEGBE  Awon onirawo ina wo loma nsaba je omo elegbe?   IRAWO INA TONKANYANRAN (ARIES) omo omi  ma nsaba po ninu irawo yi, elomiran leje emere omi abi emere igbo.... Etc..  IRAWO INA TONGBONA RIRI (LEO) elegbe ma nsaba wa ninu irawo yi na sugbon ko po bi ti akoko yen... Omo elegbe bi iranse aje,emere igbo, emere igi ogede etc...  IRAWO INA ATUPA (SAGITTARIUS) bi irawo yi se kekere to, omo elegbe toba wa ninu irawo yi ma nburu gan, aje si ma nwa lara won dada, ama n saba ri elegbe omo bi omo omi anu, igi aje, emere igbo... Sugbon omo elegbe ko wopo ninu irawo yi..      APERE FUN IRAWO INA TOJE OMO OMI  Bii onirawo Ina Baje omo Omi die ninu  Awon  apere tio fima pe omo Omi todaju nii owun . ti eru ba ma nba ninu ile ti ayare yio si maja...  Bii kii Ori ee maadede dide lainidi....  Ki o  feran lati mada soro ni onni kan... Ero okan won ma nsaba wasi imuse lopolopo igba  Iruwon lokunrin ...

AJE ARA IRAWO KOKAN ATI IBI TI AJE NA MA NWA....

Image
 AJE ARA IRAWO KOKAN ATI IBI TI AJE NA MA NWA....  Gbogbo irawo kokan loni aje tie... Ode ni ibi toma nwa lara eniyan... Yatosi awon omo elegbe.  Awon irawo kan wa tia masi irawo aje, tojepe dandan ni owo lodowon (wongbodo lowo laiye won ni ona irorun)... Sugbon kadara  leyi lori irawo won ti awon abateni je bafi owo ba ogo aiye won,  Olohun wa beni eyan na wa.... Olohun lofun won lagbara lati dari aiye bose wuwon....  Laisi wahala awon agbalagba ati ogun aiye... Awon irawo yi ma nri ti aje se gan.. Tori aje yen lonje oba irawo won.... Ama so oro yi ni ojo mi tori topic kan ni loto....  EJE KIN PADA SI ORI AJE ARA IRAWO KOKAN.....  1) AJE ARA IRAWO INA  Irawo ina lama si irawo imole to ntasi nu okunkun, irawo nla ti irawo ina je.... Adari aiye pelu imo ati opolo niwon..... Akoda onirawo ina latiwa je ero eyin tori eniwaju niwon... Onirawo yi tikoba ri ilosiwaju ninu aiye re..... Oni reason  Afowofa, ewo jije, ogun aiye tabi ogun idile, a...

ASIRI TOWA LARIN IRAWO INA ATI ERUPE

Image
 ASIRI TOWA LARIN IRAWO INA ATI ERUPE Àwọn ènìyàn kan nii irawo ina kogbodo fẹ irawo erupẹ  Bé sini awon eniyan kan nii won lè fẹ arawọn  EJEKI ASORO NIPE IRAWO INÁ ATI ERUPẸ  Njẹ iwọ mọ pé kii ùn se gbogbo ipin irawo yi nii won lè fẹ arawọn tabi da iṣẹ pọ nitori pe wahala amasele siwọn Opolopo igba ni moti ma nsofun awon eyan pe... Irawo erupe ati irawo ina kogba ti arawon.....  Inira ti irawo ina amafun erupe kise kekere, iyanje mapo, ti erupe na babinu, ija mawa di ija igboro,  Kosi nkan tiwon lemase fun arawon ni tidada.. Bi alaima se nani,....  Ija ati wahala ni gbogbo igba.... Ayafi ti irawo erupe bale ni suuru gidigan.. Sugbon kosi bi erupe sele ni suuru to.... Irawo ina matan ni suuru nani 😂.... Ki olohun towa sona 🙏 AWON NKAN TIAMA SELE SI IRAWO ERUPE ATI INA TIWON BA FERAWON.....  IRAWO INA TONKANYANRAN (ARIES) PELU IRAWO ERUPE FUNFUN (VIRGO) ti irawo ina Aries bafe erupe funfun Osese ki gbogbo aje ara Virgo tiama si erupe funfun masi...

ASIRI IRAWO AFEFE

Image
 ASIRI IRAWO AFEFE LAPAPO(GENERAL SECRETS BEHIND AIR SIGNS) Arin irin ajo aiye, oni mimo aiye, ojogbon eniyan, cel celebrities ebrities ma npo ninu won, irawo lile ni irawo yi.. Ori won sima nle, lafi ni kiwon ma bo ori won dada.... Ogun okin sise lara apakan ninu irawo yi.... Awon agbalagba omo na po ninu irawo yi  Opolopo won ama ni idojuko ati isoro topo gan Debi ipe aiye afe suwon... Sugbon tiwon base gun pere... Aiye afi olawon toro ni... Bi ola  ati okiki won ase to.. Sugbon opolopo won koma oju ona. Oba ni irawo yi je lawujo irawo toku, alagbara tio mawa nipo nla nla niwon, won osimari ero ngbawon lopin igbati wonkobati je ewo(forbidden) tabi lonkan ewo tabi se nkan ewo. Ogun okin sise lara opolopo won tori iseda won lagbara gan ori won sile... Tori re lofise pataki kiwon ma bo ori won...  Saara sise se dandan funwon tori ki ona maba madimawon.. Kiwon ma se saara dada leyi toba iseda irawo won mun tori kiwon maba mari ifaseyin ninu irin ajo aiye won..  Wo...